quinta-feira, 28 de julho de 2016

Sociologia

Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ (sociologia)

A Sociologia é a ciência que se dedica a estudar e compreender os fenômenos sociais atrelados às nossas relações sociais.




Àwọn ọ̀rọ̀-ìjàníyàn àwùjọ (questões sociais).



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


1. Ètòìlú àwùjọ (política social).
2. Ìpele àwùjọ (estrutura social).
3. Ìtòlẹ́se àwùjọ (estratificação social).
4. Àtòsọ́tọ̀ àwùjọ (classe social).
5. Àṣà (costume, hábito, moda).
6. Ìyípòpadà àwùjọ (mobilidade social).
7. Ẹ̀sìn (religião).
8. Ìsọditaráayé (secularização).
9. Òfin (lei).
10. Ìyájú àwùjọ (desvio social).
11. Àdìmúlẹ̀ àwùjọ (instituição social).
12. Ìjẹníyà àwùjọ (punição social).
13. Orí íńtánẹ́ẹ̀tì (internet).
14. Àṣàpúpọ̀ (multiculturalismo).
15. Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹ̀yà ènìyàn (sociedade multiétnica).
16. Ogun abẹ́lé (guerra civil).
17. Ogun (Guerra).
18. Ìjídìde (revolução).
19. Ìjọba (governo, reino).
20. Irú ìjọba (forma de governo).
21. Ìjàkádì ipò (luta de classes).
22. Ìdájọ́ (justiça).
23. Àláfíà (paz).
24. Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn (direitos humanos).
25. Òfin káríayé (direito internacional).
26. Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn (  Declaração Universal dos Direitos Humanos).
27. Àgbájọ (organização).
28. Ọ̀rọ̀-òfin (jurisprudência).
29. Àwọn ọ̀nà ìmúwàyé (meios de produção).
30. Àwọn ẹ̀tọ́ ẹ̀dá (direitos naturais).
31. Àdéhún àwùjọ, májẹ̀mú àwùjọ (contrato social).
32. Ìfigbakágba àwùjọ (conflito social).
33. Ìjagun (combate).
34. Jàgídíjàgan (violência).
35. Ìwà ọ̀daràn (criminalidade).
36. Ọ̀rọ̀àbá (ideologia).
37. Àgbájọ abófinmu (organização jurídica).
38. Àwọn àgbájọ aláìjẹ́-tìèrè (Instituições sem fins lucrativos).
39. Àwọn àgbájọ aláìjẹ́-tìjọba (Organizações não governamentais).
40. Àwọn ọ̀págun ISO (Normas ISO).
41. Àgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págun (Organização Internacional para Padronização).
42. Àgbájọ Akáríayé Okun Átọ́mù (Agência Internacional de Energia Atômica).
43. Àjọ Ètò Owó Káríayé (Fundo Monetário Internacional).
44. Atòlànà kọ̀mpútà ọ̀fẹ́ (software livre).
45. Àwọn àkọọ́lẹ̀ (convenções culturais).
46. Àwọn ìwé àṣẹ (licenças).
47. Àwọn ìwé àṣẹ ẹ̀tọ́àwòkọ (Licenças de direitos autorais).
48. Ìṣeékàsí àwùjọ (responsabilidade social).
49. Ìwàìbàjẹ́, ìwàìbàjẹ́ olóṣèlú  (corrupção).
50. Ìṣekọ́múnístì (comunismo).
51. Ìṣesósíálístì (socialismo).
52. Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé (capitalismo).
53. Ogun sí Ìṣedánilóró (guerra ao terrorismo).
54. Olùdánilóró (terrorista).
55. Ìṣedánilóró (terrorismo).
56. Ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró (ataques ou atentado terrorista).
57. Ìṣetọlọ́ba (monarquismo).
58. Ọlọ́ba, àdájọba, ìdọ́bajẹ (monarquia).
59. Ilẹ̀ ọbalúayé (império).
60. Ìjọba ológun (governo militar).
61. Ìjọba àìlólórí (anarquismo).
62. Òṣèlúaráìlú (democracia).
63. Ọlọ́ba pátápátá (monarquia absoluta).
64. Ọlọ́ba onílànàìrẹ́pọ̀ (monarquia constitucional).
65. Òṣèlúaráìlú òṣèlú aṣojú (democracia representativa).
66. Orílẹ̀-èdè olómìnira (república).
67. Òṣèlú aláwùjọ (social-democracia).
68. Àjọṣepọ̀ (federação).
69. Ìṣeolómìnira ijọ́hun (republicanismo clássico).
70. Ọ̀làjú (iluminismo, civilização).
71. Alágbáláayé (universalista).
72. Àgbáláayé (universal).
74. Àwọn aṣèwadìí àwùjọ (investigações sociais).
75. Aṣèwadìí ìdárasí (pesquisa qualitativa).
76. Aṣèwadìí ìpòsí (pesquisa quantitativa).
77. Àròjinlẹ̀ (teoria).
78. Ìmọ̀ sáyẹ́nsì (conhecimento científico).
79. Aṣeròjinlẹ̀ olóṣèlú (teórico político).
80. Aṣeọ̀rọ̀-òkòwò olóṣèlú (economista político).
81. Aṣeọ̀rọ̀-àwùjọ, onímọ̀ àwùjọ (sociólogo).
82. Manifẹ́stò Kómúnístì (manifesto comunista).
83. Ìmòye olóṣèlú, ìmọ̀-òye olóṣèlú (filosofia política).
84. Àwọn ọmọẹgbẹ́ (membros).
85. Àbíníbí ará Amẹ́ríkà (nativo americano).
86. Ogun Àgbáyé (Gerra mundial).
87. Ogun Àgbáyé Kìíní (primeira guerra mundial).
88. Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì, Ogun Àgbáyé Kejì ( segunda guerra mundial).
89. Oko ẹrú, òwò ẹrú, títà àti ríra ènìyàn (escravidão, escravatura).
90. Ẹrú (escravo).
91. Ilẹ̀ọbalúayé, ilẹ̀-Ọba, ilẹ̀jọba (império).
92. Ìṣàgbéṣe ẹnìkọ̀kan (agência).
93. Àdìmúlẹ̀ ìlera (instituição de saúde).
94. Oníwòsàn (médico).
95. Ológun (militar).
96. Oníkékeré ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ (microssociologia).
97. Oníkékeré ìṣàgbéṣe (micro agência).
98. Onígbàngbà ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ (macrossociologia).
99. Sáyẹ́nsì àwùjọ (ciência social).
100. Àwùjọ (sociedade).
101. Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì (Racista).
102. Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà (racismo).
103. Àgbájọ àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan (Organização das Nações Unidas). 

Nenhum comentário:

Postar um comentário