domingo, 8 de fevereiro de 2015

Dragão

Mo sì rí ẹranko ẹhànnà mìíràn tí ń gòkè bọ̀ láti inú ilẹ̀ ayé, ó sì ní ìwo méjì bí ọ̀dọ́ àgùntàn, ṣùgbọ́n ó bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ bí dírágónì.
  E eu vi outra fera ascender da terra, e ela tinha dois chifres semelhantes aos dum cordeiro, mas começou a falar como dragão. Apocalipse, 13: 11




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

1 - Mo sì rí ẹranko ẹhànnà mìíràn.
 E eu vi outra fera.
2 -Tí ń gòkè bọ̀ láti inú ilẹ̀ ayé.
 Ascender da terra.
3 - Ó sì ní ìwo méjì bí ọ̀dọ́ àgùntàn
 E ela tinha dois chifres semelhantes aos dum cordeiro.
4- Ṣùgbọ́n ó bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ bí dírágónì.
Mas começou a falar como dragão.

Nenhum comentário:

Postar um comentário